Popular Posts

Wednesday, 13 January 2016

O SOGE SE

Oti gbagbe pe
Omo dudu gbayi lawujo
Adu ma 'a dan
Afi bi ti koro shin
Girisi lasan ti to o para

O ko romo ile ookan
Boyo lokankan
Awon okunrin a si boyin
Won a fe fi saya

Awo to wuni lopolopo
Ni dudu osun je

Omo dudu t'o n bora
O wa da bi ebora
Ma so pe o ko gbo
Ohun ti pasito fi preach
Se lo fi gbigbo
Se alaigbo
Nigbati o wa lo bleach
Iyen nigba t'o bora tan
So fun mi ki lo jo na

Ogede pipon to pon
Inu re baje
Ita re dudu
Loju re oti pon
Sugbon omo dudu si loje

To ba wa ya
Wa d'a lawo meji
Asin de orun de

O je s'ora oge 'se
Ko s'oge mo ni won

O bewaje je
Iyi ko si mo
O ma se o...

#gbemieth

No comments:

Post a Comment